Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 15:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla na si gòke lọ si Debiri lati afonifoji Akoru, ati bẹ̃ lọ si ìha ariwa, ti o dojukọ Gilgali, ti mbẹ niwaju òke Adummimu, ti mbẹ ni ìha gusù odò na: àla si kọja si apa omi Eni-ṣemeṣi, o si yọ si Eni-rogeli:

Ka pipe ipin Joṣ 15

Wo Joṣ 15:7 ni o tọ