43. Ati Ifta, ati Aṣna, ati Nesibu;
44. Ati Keila, ati Aksibu, ati Mareṣa; ilu mẹsan pẹlu ileto wọn.
45. Ekroni, pẹlu awọn ilu rẹ̀ ati awọn ileto rẹ̀:
46. Lati Ekroni lọ ani titi dé okun, gbogbo eyiti mbẹ leti Aṣdodu, pẹlu ileto wọn.
47. Aṣdodu, pẹlu ilu rẹ̀ ati ileto rẹ̀; Gasa, pẹlu ilu rẹ̀ ati ileto rẹ̀; dé odò Egipti, ati okun nla, ati àgbegbe rẹ̀.
48. Ati ni ilẹ òke, Ṣamiri, ati Jattiri, ati Soko;
49. Ati Dana, ati Kiriati-sana (ti ṣe Debiri);
50. Ati Anabu, ati Eṣtemo, ati Animu;
51. Ati Goṣeni, ati Holoni, ati Gilo; ilu mọkanla pẹlu ileto wọn.
52. Arabu, ati Duma, ati Eṣani;
53. Ati Janimu, ati Beti-tappua, ati Afeka;