Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 15:43-47 Yorùbá Bibeli (YCE)

43. Ati Ifta, ati Aṣna, ati Nesibu;

44. Ati Keila, ati Aksibu, ati Mareṣa; ilu mẹsan pẹlu ileto wọn.

45. Ekroni, pẹlu awọn ilu rẹ̀ ati awọn ileto rẹ̀:

46. Lati Ekroni lọ ani titi dé okun, gbogbo eyiti mbẹ leti Aṣdodu, pẹlu ileto wọn.

47. Aṣdodu, pẹlu ilu rẹ̀ ati ileto rẹ̀; Gasa, pẹlu ilu rẹ̀ ati ileto rẹ̀; dé odò Egipti, ati okun nla, ati àgbegbe rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 15