Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 15:32-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

32. Ati Lebaotu, ati Ṣilhimu, ati Aini, ati Rimmoni: gbogbo ilu na jasi mọkandilọgbọ̀n, pẹlu ileto wọn.

33. Ni pẹtẹlẹ̀, Eṣtaoli, ati Sora, ati Aṣna;

34. Ati Sanoa, ati Eni-gannimu Tappua, ati Enamu;

35. Jarmutu, ati Adullamu, Soko, ati Aseka;

Ka pipe ipin Joṣ 15