30. Ati Eltoladi, ati Kesili, ati Horma;
31. Ati Siklagi, ati Madmanna, ati Sansanna;
32. Ati Lebaotu, ati Ṣilhimu, ati Aini, ati Rimmoni: gbogbo ilu na jasi mọkandilọgbọ̀n, pẹlu ileto wọn.
33. Ni pẹtẹlẹ̀, Eṣtaoli, ati Sora, ati Aṣna;
34. Ati Sanoa, ati Eni-gannimu Tappua, ati Enamu;
35. Jarmutu, ati Adullamu, Soko, ati Aseka;
36. Ati Ṣaaraimu, ati Aditaimu, ati Gedera, ati Gederotaimu; ilu mẹrinla pẹlu ileto wọn.
37. Senani, ati Hadaṣa, ati Migdali-gadi;
38. Ati Dilani, ati Mispe, ati Jokteeli;
39. Lakiṣi, ati Boskati, ati Egloni;
40. Ati Kabboni, ati Lamamu, ati Kitliṣi;
41. Ati Gederotu, Beti-dagoni, ati Naama, ati Makkeda; ilu mẹrindilogun pẹlu ileto wọn.