Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 15:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati fun Kalebu ọmọ Jefunne li o fi ipín fun lãrin awọn ọmọ Juda, gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA fun Joṣua, ani Kiriati-arba (ti iṣe Hebroni); Arba si ni baba Anaki.

Ka pipe ipin Joṣ 15

Wo Joṣ 15:13 ni o tọ