Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 15:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla na yi lati Baala lọ si ìha ìwọ-õrùn si òke Seiri, o si kọja lọ si ẹba òke Jearimu (ti ṣe Kesaloni), ni ìha ariwa, o si sọkalẹ lọ si Beti-ṣemeṣi, o si kọja lọ si Timna:

Ka pipe ipin Joṣ 15

Wo Joṣ 15:10 ni o tọ