Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si bura li ọjọ́ na wipe, Nitõtọ ilẹ ti ẹsẹ̀ rẹ ti tẹ̀ nì, ilẹ-iní rẹ ni yio jẹ́, ati ti awọn ọmọ rẹ lailai, nitoriti iwọ tọ̀ OLUWA Ọlọrun mi lẹhin patapata.

Ka pipe ipin Joṣ 14

Wo Joṣ 14:9 ni o tọ