Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 14:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ẹ̀ya meji ni ẹ̀ya awọn ọmọ Josefu, Manasse ati Efraimu: nitorina nwọn kò si fi ipín fun awọn ọmọ Lefi ni ilẹ na, bikoṣe ilu lati ma gbé, pẹlu àgbegbe ilu wọn fun ohunọ̀sin wọn ati ohun-iní wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 14

Wo Joṣ 14:4 ni o tọ