Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 14:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nitorina fi òke yi fun mi, eyiti OLUWA wi li ọjọ́ na; nitoriti iwọ gbọ́ li ọjọ́ na bi awọn ọmọ Anaki ti wà nibẹ̀, ati ilu ti o tobi, ti o si ṣe olodi: bọya OLUWA yio wà pẹlu mi, emi o si lé wọn jade, gẹgẹ bi OLUWA ti wi.

Ka pipe ipin Joṣ 14

Wo Joṣ 14:12 ni o tọ