Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 13:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹ̀ya Lefi ni Mose kò fi ilẹ-iní fun: OLUWA, Ọlọrun Israeli, ni iní wọn, gẹgẹ bi o ti wi fun wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 13

Wo Joṣ 13:33 ni o tọ