Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 13:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ilẹ ọba Ogu ni Baṣani, ti o jọba ni Aṣtarotu ati ni Edrei, ẹniti o kù ninu awọn Refaimu iyokù: nitori awọn wọnyi ni Mose kọlù, ti o si lé jade.

Ka pipe ipin Joṣ 13

Wo Joṣ 13:12 ni o tọ