Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Joṣua kọlù gbogbo ilẹ, ilẹ òke, ati ti Gusù, ati ti pẹtẹlẹ̀, ati ti ẹsẹ̀-òke, ati awọn ọba wọn gbogbo; kò kù ẹnikan silẹ: ṣugbọn o pa ohun gbogbo ti nmí run patapata, gẹgẹ bi OLUWA, Ọlọrun Israeli, ti pa a laṣẹ.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:40 ni o tọ