Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kó o li ọjọ́ na, nwọn si fi oju idà kọlù u, ati gbogbo ọkàn ti mbẹ ninu rẹ̀ li o parun patapata li ọjọ́ na, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ṣe si Lakiṣi.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:35 ni o tọ