Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si fi Lakiṣi lé Israeli lọwọ, o si kó o ni ijọ́ keji, o si fi oju idà kọlù u, ati gbogbo ọkàn ti o wà ninu rẹ̀, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ṣe si Libna.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:32 ni o tọ