Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li akokò ìwọ-õrùn, Joṣua paṣẹ, nwọn si sọ̀ wọn kalẹ kuro lori igi, nwọn si gbé wọn sọ sinu ihò na ninu eyiti nwọn ti sapamọ́ si, nwọn si fi okuta nla di ẹnu ihò na, ti o wà titi di oni-oloni.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:27 ni o tọ