Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ṣe bẹ̃, nwọn si mú awọn ọba mararun nì jade lati inu ihò na tọ̀ ọ wá, ọba Jerusalemu, ọba Hebroni, ọba Jarmutu, ọba Lakiṣi, ati ọba Egloni.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:23 ni o tọ