Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Joṣua wi fun OLUWA li ọjọ́ ti OLUWA fi awọn Amori fun awọn ọmọ Israeli, o si wi li oju Israeli pe, Iwọ, Õrùn, duro jẹ lori Gibeoni; ati Iwọ, Oṣupa, li afonifoji Aijaloni.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:12 ni o tọ