Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si fọ́ wọn niwaju Israeli, o si pa wọn ni ipakupa ni Gibeoni, o si lepa wọn li ọ̀na òke Beti-horoni, o si pa wọn dé Aseka, ati dé Makkeda.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:10 ni o tọ