Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI ṣe, nigbati Adoni-sedeki ọba Jerusalemu gbọ́ pe Joṣua ti kó Ai, ti o si pa a run patapata; bi o ti ṣe si Jeriko ati si ọba rẹ̀, bẹ̃li o si ṣe si Ai ati si ọba rẹ̀; ati bi awọn ara Gibeoni ti bá Israeli ṣọrẹ, ti nwọn si ngbé ãrin wọn;

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:1 ni o tọ