Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki yio sí ọkunrin kan ti yio le duro niwaju rẹ li ọjọ́ aiye rẹ gbogbo: gẹgẹ bi mo ti wà pẹlu Mose, bẹ̃li emi o si wà pẹlu rẹ: Emi ki yio fi ọ silẹ, bẹ̃li emi ki yio kọ̀ ọ.

Ka pipe ipin Joṣ 1

Wo Joṣ 1:5 ni o tọ