Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Titi OLUWA yio fi fun awọn arakunrin nyin ni isimi, gẹgẹ bi o ti fi fun nyin, ati ti awọn pẹlu yio fi gbà ilẹ na ti OLUWA Ọlọrun nyin fi fun wọn: nigbana li ẹnyin o pada si ilẹ iní nyin, ti Mose iranṣẹ OLUWA fi fun nyin ni ìha ihin Jordani ni ìha ìla-õrùn, ẹnyin o si ní i.

Ka pipe ipin Joṣ 1

Wo Joṣ 1:15 ni o tọ