Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ mã ṣọra, olukuluku nyin lọdọ aladugbo rẹ̀, ki ẹ má si gbẹkẹle arakunrin karakunrin: nitoripe olukuluku arakunrin fi arekereke ṣẹtan patapata, ati olukuluku aladugbo nsọ̀rọ ẹnilẹhin.

Ka pipe ipin Jer 9

Wo Jer 9:4 ni o tọ