Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 9:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki ẹnikẹni ti yio ba ma ṣogo, ki o ṣe e ninu eyi pe: on ni oye, on si mọ̀ mi; pe, Emi li Oluwa ti nṣe ãnu ati idajọ ati ododo li aiye: nitori inu mi dùn ninu ohun wọnyi, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 9

Wo Jer 9:24 ni o tọ