Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 9:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fun awọn oke-nla ni emi o gbe ẹkún ati ohùnrere soke, ati ẹkún irora lori papa oko aginju wọnnì, nitoriti nwọn jona, ẹnikan kò le kọja nibẹ, bẹ̃ni a kò gbọ́ ohùn ẹran-ọsin, lati ẹiyẹ oju-ọrun titi de ẹranko ti sa kuro, nwọn ti lọ.

Ka pipe ipin Jer 9

Wo Jer 9:10 ni o tọ