Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo tẹti lélẹ, mo si gbọ́, ṣugbọn nwọn kò sọ̀rọ titọ: kò si ẹnikan ti o ronupiwada buburu rẹ̀ wipe, kili emi ṣe? gbogbo nwọn yipo li ọ̀na wọn, bi akọ-ẹṣin ti nsare gburu sinu ogun.

Ka pipe ipin Jer 8

Wo Jer 8:6 ni o tọ