Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 7:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn eyi ni mo paṣẹ fun wọn wipe, Gba ohùn mi gbọ́, emi o si jẹ Ọlọrun nyin, ẹnyin o si jẹ enia mi: ki ẹ si rin ni gbogbo ọ̀na ti mo ti paṣẹ fun nyin, ki o le dara fun nyin.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:23 ni o tọ