Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 7:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina máṣe gbadura fun enia yi, bẹ̃ni ki o má si gbe igbe rẹ soke ati adura fun wọn, bẹ̃ni ki o má ṣe rọ̀ mi: nitori emi kì yio gbọ́ tirẹ.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:16 ni o tọ