Ẹ ya ara nyin si mimọ́ lati ba a jagun; dide, ki ẹ si jẹ ki a goke li ọsan. Egbe ni fun wa! nitori ọjọ nlọ, nitori ojiji ọjọ alẹ nà jade.