Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 6:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi kún fun ikannu Oluwa, ãrẹ̀ mu mi lati pa a mọra: tu u jade sori ọmọde ni ita, ati sori ajọ awọn ọmọkunrin pẹlu: nitori a o mu bãle pẹlu aya rẹ̀ ni igbekun, arugbo pẹlu ẹniti o ni ọjọ kikún lori.

Ka pipe ipin Jer 6

Wo Jer 6:11 ni o tọ