Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 52:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, li ọdun kẹtadilogoji Jehoiakimu, ọba Juda, li oṣu kejila, li ọjọ kẹdọgbọn oṣu, Efil-Merodaki, ọba Babeli, li ọdun ekini ijọba rẹ̀, o gbe ori Jehoiakimu, ọba Juda, soke, o si mu u jade ninu ile túbu.

Ka pipe ipin Jer 52

Wo Jer 52:31 ni o tọ