Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 50:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o ma bère ọ̀na Sioni, oju wọn yio si yi sibẹ, nwọn o wá, nwọn o darapọ mọ Oluwa ni majẹmu aiyeraiye, ti a kì yio gbagbe.

Ka pipe ipin Jer 50

Wo Jer 50:5 ni o tọ