Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 50:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o di ọrun ati ọ̀kọ mu: onroro ni nwọn, nwọn kì o si ṣe ãnu: ohùn wọn yio ho gẹgẹ bi okun, nwọn o si gun ori ẹṣin lẹsẹsẹ, nwọn si mura bi ọkunrin ti yio jà ọ logun, iwọ ọmọbinrin Babeli.

Ka pipe ipin Jer 50

Wo Jer 50:42 ni o tọ