Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 50:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, pe, awọn ọmọ Israeli ati awọn ọmọ Juda li a jumọ pọn loju pọ̀: gbogbo awọn ti o kó wọn ni ìgbekun si di wọn mu ṣinṣin; nwọn kọ̀ lati jọ wọn lọwọ lọ.

Ka pipe ipin Jer 50

Wo Jer 50:33 ni o tọ