Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, oju rẹ kò ha wà lara otitọ? iwọ ti lù wọn, ṣugbọn kò dùn wọn; iwọ ti run wọn, ṣugbọn nwọn kọ̀ lati gba ẹkọ: nwọn ti mu oju wọn le jù apata lọ; nwọn kọ̀ lati yipada.

Ka pipe ipin Jer 5

Wo Jer 5:3 ni o tọ