Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si Edomu. Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; Kò ha si ọgbọ́n mọ ni Temani? a ha ke imọran kuro lọdọ oloye? ọgbọ́n wọn ha danu bi?

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:7 ni o tọ