Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, emi o mu ẹ̀ru wá sori rẹ, li Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun wi, lati ọdọ gbogbo awọn wọnni ti o wà yi ọ kakiri; a o si le nyin, olukuluku enia tàra niwaju rẹ̀; ẹnikan kì o si kó awọn ti nsalọ jọ.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:5 ni o tọ