Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi o mu Elamu warìri niwaju awọn ọta wọn, ati niwaju awọn ti nwá ẹmi wọn: emi o si mu ibi wá sori wọn, ani ibinu gbigbona mi, li Oluwa wi; emi o si rán idà tẹle wọn, titi emi o fi run wọn.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:37 ni o tọ