Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Agọ wọn ati agbo-ẹran wọn ni nwọn o kó lọ: nwọn o mu aṣọ agọ wọn fun ara wọn, ati gbogbo ohun-èlo wọn, ati ibakasiẹ wọn; nwọn o si kigbe sori wọn pe, Ẹ̀ru yikakiri!

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:29 ni o tọ