Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, wò o, ọjọ mbọ̀, li Oluwa wi, ti emi o mu ki a gbọ́ idagiri ogun ni Rabba ti awọn ọmọ Ammoni: yio si di okiti ahoro, a o si fi iná sun awọn ọmọbinrin rẹ̀; nigbana ni Israeli yio jẹ arole awọn ti o ti jẹ arole rẹ̀, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:2 ni o tọ