Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibanilẹ̀ru rẹ ti tan ọ jẹ, igberaga ọkàn rẹ, nitori iwọ ngbe palapala okuta, ti o joko li ori oke, bi iwọ tilẹ kọ́ itẹ́ rẹ ga gẹgẹ bi idì, sibẹ emi o mu ọ sọkalẹ lati ibẹ wá, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:16 ni o tọ