Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi; Wò o, awọn ẹniti kò jẹbi, lati mu ninu ago, ni yio mu u lõtọ: iwọ o ha si lọ li alaijiya? iwọ kì yio lọ li alaijiya, nitori lõtọ iwọ o mu u.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:12 ni o tọ