Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 46:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wipe; Wò o, emi o bẹ̀ Amoni ti No, ati Farao, ati Egipti wò, pẹlu awọn ọlọla wọn, ati awọn ọba wọn; ani Farao ati gbogbo awọn ti o gbẹkẹ le e:

Ka pipe ipin Jer 46

Wo Jer 46:25 ni o tọ