Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu eyiti ẹnyin fi iṣẹ ọwọ nyin mu mi binu, ni sisun turari fun ọlọrun miran ni ilẹ Egipti, nibiti ẹnyin lọ lati ṣatipo, ki ẹ le ke ara nyin kuro, ati ki ẹ le jẹ ẹni-ègun ati ẹsin, lãrin gbogbo orilẹ-ède ilẹ aiye?

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:8 ni o tọ