Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni mo ṣe dà ìrunu mi ati ibinu mi jade, a si daná rẹ̀ ni ilu Juda, ati ni ita Jerusalemu: nwọn si di ofo ati ahoro, gẹgẹ bi ti oni yi.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:6 ni o tọ