Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa wi; wò o, emi o fi Farao-hofra, ọba Egipti, le ọwọ awọn ọta rẹ̀, ati le ọwọ awọn ti nwá ẹmi rẹ̀; gẹgẹ bi emi ti fi Sedekiah, ọba Juda, le ọwọ Nebukadnessari, ọba Babeli ọta rẹ̀, ti o si wá ẹmi rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:30 ni o tọ