Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa, gbogbo Juda ti ngbe ilẹ Egipti, sa wò o, emi ti fi orukọ nlanla mi bura, li Oluwa wi, pé, a kì yio pè orukọ mi li ẹnu ọkunrin-kunrin Juda ni gbogbo ilẹ Egipti, wipe, Oluwa, Ọlọrun wà.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:26 ni o tọ