Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 41:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọkunrin mẹwa wà lãrin wọn ti nwọn sọ fun Iṣmaeli pe, máṣe pa wa: nitori awa ni iṣura li oko, ti alikama, ati ti ọka barli, ati ti ororo, ati oyin. Bẹ̃li o jọwọ wọn, kò si pa wọn pẹlu awọn arakunrin wọn.

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:8 ni o tọ