Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 41:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o wà pẹlu rẹ̀, si mu gbogbo iyokù awọn enia ti o ti gbà lọwọ Iṣmaeli, ọmọ Netaniah, lati Mispa, lẹhin ti o ti pa Gedaliah, ọmọ Ahikamu ani, akọni ọkunrin ogun, ati awọn obinrin, ati awọn ọmọde, ati awọn iwẹfa, awọn ti o ti tun mu pada lati Gibeoni wá:

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:16 ni o tọ