Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 41:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iṣmaeli si kó gbogbo iyokù awọn enia ti o wà ni Mispa ni igbekun, awọn ọmọbinrin ọba, ati gbogbo enia ti o kù ni Mispa, awọn ti Nebusaradani, balogun iṣọ, ti fi le Gedaliah, ọmọ Ahikamu lọwọ: Iṣmaeli, ọmọ Netaniah, si kó wọn ni igbekun, o si kuro nibẹ lati rekọja lọ sọdọ awọn ọmọ Ammoni.

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:10 ni o tọ